Digitox

Gba ìṣàkóso lórí fóònù rẹ

Ṣètò òdiwọ̀n lórí àwọn áàpù,àkóónú àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ!!

Dẹ́kun ìwà burúkú.

Àfẹ́ẹ̀fẹ́jù àwọn áàpù le dín àfojúsùn rẹ kù.

Digitox jẹ́ áàpù tí a ṣé láti jẹ́ kí o pa ọkàn pọ̀.

★★★★★
"Mo ṣẹṣẹ ṣìí áàpù yìí ni, láàrin ìṣẹ́jú àáyá ọgbọ̀n, ó jọ ohun ti màá nífẹ sí.. Ó fẹ̀yìn àwọn áàpù mìíràn balẹ̀. Ṣe igbasilẹ rẹ ki o wo fun ara rẹ. "

— Ìgbéléwọ̀n Play Store

★★★★★
"Mo le lo àwọn áàpù oníyíyí lẹekansi, yóò ṣàfihàn ara rẹ̀ láti maje kí n kọjá òdiwọ̀n ojoojúmọ́ mi. Ó jẹ́ olùyípadà ohun gbogbo fún mi. "

— Ìgbéléwọ̀n Play Store

★★★★★
”Mo dáàbá áàpù yìí fún ọ̀arẹ́ mi, ó sì sọpé áàpù yìí je ọ̀kan nínú àwọn ohun tí o dara ti mo ti pín pẹ̀lú òun.”

— Ìgbéléwọ̀n Play Store

Gba iṣakoso pada

Digitox máa ń jẹ́ kí o ṣètò gbèdéke lórí àkóónú, kì í ṣe àwọn áàpù nìkan.

Ṣé o fẹ́ dín òṣèlú kù nínú ayé rẹ? Ṣé o fẹ́ dín fídíò kúkurú YouTube kù? Òun nìyi!

Fi sórí ẹ̀rọ

Ṣètò kí o sì gbàgbé

Ìṣètò rọrùn gan-an.

Digitox máa ń ṣiṣẹ́ lábẹ́lẹ̀ ó sì rántí àwọn ààtò rẹ.

Fi sórí ẹ̀rọ

Fi ìdánimọ̀ rẹ pamọ́

Kò sí àkáùntì, kò sí káàdì ìsanwó, kò sí ìdánimọ̀. Digitox kò ní gba infọmésàn rẹ.

Fi sórí ẹ̀rọ

Darapọ̀ mọ́ àkójọ-ìdúróde iOS

Tabi ki o ṣafikun imeeli rẹ ti o ba fẹ duro de afikun!